Wednesday, June 8

Kai...

E ma kaya ja mi,
Mi o fe se yin,
Sugbon mi o ki n se omode mo,
E wo mi pelu oju agba,
Gege bi ore yin,
Se'beyin le wi pe ore ni wa,
L'oto le wipe emi o ki n se ore gidi,
Sugbon e ma da imule wa ru,
E ma se eyi.

O l'ewu.
O l'ewu fun eyin,
O l'ewu fun emi naa.

Ere ya lese mi,
Mi n ki pe sa,
Nitoripe, ti aya mi ba ti ja,
Okan mi ma n sa lo
E ma le mi
L'ooto le nife mi,
Sugbon, ife omode le ni si mi
nigbati o je wipe ife agba ni emi fe.

E ma seyi!

2 comments:

Ore_Oluwa said...

I love it!

NaijaScorpio said...

How did u deal with the abanla situation?